Lati Inu Dáyárì Ọmọ Kilásì Àárin Kan by Ashok Kumawat
Synopsis
Àpèjúwe Kúkúrú
Ninu ìwé yii Mo ti ṣàpèjúwe awọn akitiyan igbé ayé mi ni kọlẹji. Mo pinnu lati kọ ìwé yi nigbati ó jẹ wipe n kò ni awọn ọrẹ, n kò mọ bi awọn ìdánwò ipari simẹsità ti yunifásítì se ri, ti mo si pàdánù awọn ìdánwò mi. Lẹhin ọpọlọpọ akitiyan, mo se awọn ìdánwò ipari simẹsità, mo si kọ awọn iriri mi ni kọlẹji sinu ìwé yi.
Àpèjúwe Ní Kíkún

Reviews
Write your review
Wanna review this e-book? Please Sign in to start your review.